letra de happy people - aṣa
o òré mi láídé
níbo ló dà l’ójó sat-rday yìí
hmmm… wón se party níhìn o
l’ókè súnáà léhìn kùlé àwon làtí
ànkárá la dá
kòstúmù la wò
kosé l’afi gbóyàn sókè
bàtà mí ti ready
ànkárá la dá
kòstúmù la wò
kosé l’afi gbóyàn sókè
bàtà mí ti ready
oh we’re happy people
and that’s who we are
we’re having fun
we’re the children of the sun
oh we’re happy people
and that’s who we are
we don’t care
we’re the children of the sun
o òré mi laide
níbo ló kàn l’ójó sunday yìí
hmmm… wón gbéyàwó níhin o
l’ókè pópó légbe ilé àwon toyeeb
ànkárá la dá
kòstúmù la wò
kosé l’afi gbóyàn sókè
bàtà mí ti ready
ànkárá la dá
gèlè búlúù la wò
kosé l’afi gbóyàn sókè
bàtà mí ti ready
oh we’re happy people
and that’s who we are
we’re having fun
we are the children of the sun
oh oh we happy people
and that’s who we are
we don’t care
we are the children of the sun
oh oh we happy people
and that’s who we are
we’re having fun
we are the children of the sun
oh oh we happy people
and that’s who we are
oh we don’t care
we are the children of the sun
oh oh we happy people
and that’s who we are now
oh we don’t care
we are the children of the sun
letras aleatórias
- duncan sheik › letra de life's what you make it - duncan sheik
- the manhattan transfer › letra de route 66 - the manhattan transfer
- nena › letra de es regnet (new version) - nena
- mary lou lord › letra de old tin tray - mary lou lord
- billy joe shaver › letra de that's why the man in black sings the blues - billy joe shaver
- maija vilkkumaa › letra de jouluriita (vain elämää joulu) - maija vilkkumaa
- galahad › letra de richelieus prayer - galahad
- danza invisible › letra de cualquiera de nosotros (en equilibrio) - danza invisible
- the bosshoss › letra de jelly bean - the bosshoss
- steve forbert › letra de in the jailhouse now number 1 - steve forbert