letras.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

letra de bata wahala (feat. loveless & lyrical) - yung jxu

Loading...

solo – made
solomade
gbogbo beat yìí máa mi npariwo sí mí létí ke

àkó mí nmu olorogbo labe
ìgi lát’àárò ni ehn
mí dé wa understand gbogbo
nkan tó wà mí nsele bayii
brother mí kìí tii ri
kìí tii kìí happen
asorogbayi l’omo nà

ti eyin ba tesumole
àwa nma yago f’esu
torí mio fẹ ní issue oh
k’olowo mi
má pàdà sha tissue oh
ti eyin ba tesumole
àwa nma yago f’esu
torí mio fẹ ní issue oh
k’olowo mi
má pàdà sha tissue oh
bàtà wàhálà
bàtà wàhálà
torí eni t’oun w’owo ọlọrun
ko kin wa wàhálà woos
ma fa loud kàkà kí n’fa wàhálà
ọmọ tó fúnmi ni lamba yìí
ọlọ’run wa last

wọn ní otí dá bayii
wọn ní otí dá bayii
tíó bá tí jẹ ọrọ ọwọ ló fẹ
ma sọ ogbeni kò gbà bayii
shẹ ọ mọ orúkọ mí níí
dem call me asorogbayi
cause you no borrow me money for all the things
wey you see me i buy ahán
shẹ iwo mọ t’oda t’oda
sipping the coda coda
popping the 542
pẹlú codeine náà
sinu soda soda
ọmọ ele go down go down
shẹ ọ mọ t’oda t’oda
even for lockdown lockdown
na we dey shutdown shutdown

oya na see wo
oya jii ọmọ masun
má wò bose nṣe bí ẹní
to je capsule
wọn l’oju irowo loti j’oja
ọwá lọ dá wahala le
l’eti gutter
ni ibí t’awon boko squad
tin s’aye
shẹ b’ashomu témi gbe lọlẹ
shẹ bí ìyẹn ló lọ f’obo muje
kunle poly dè lọ l’aje
ọwá lọ tá fún àwọn awawa boys

ti eyin ba tesumole
àwa nma yago f’esu
torí mio fẹ ní issue oh
k’olowo mi
má pàdà sha tissue oh
bàtà wàhálà
bàtà wàhálà
torí eni t’oun w’owo ọlọrun
ko kin wa wàhálà ah
ma fa loud kàkà kí n’fa wàhálà
ọmọ tó fúnmi ni lamba yìí
ọlọrun wa last

lodi bàtà wàhálà
wase wahala
olówó láyé mó n-gga mí
loje kín máṣe wahala
ẹni tó ṣiṣẹ lọ njere
wonpe mí ní ìjímèrè
wá fẹ kú tí mọ tí mú baby oku
ọmọ tin ba mu lale yìí
o sure p’oma dákú
wọn nwa ngbàdura
ká wá tún kú
studio làwá alè gork
bàtà wàhálà
olówó kan kín wà wahala
awọn témi gán o nwà wahala
awọn ti iwọ gán o fẹ wahala

ti eyin ba tesumole
àwa nma yago f’esu
torí mio fẹ ní issue oh
k’olowo mi
má pàdà sha tissue oh
bàtà wàhálà
bàtà wàhálà
torí eni t’oun w’owo ọlọrun
ko kin wa wàhálà woos
ma fa loud kàkà kí n’fa wàhálà
ọmọ tó fúnmi ni lamba yìí
ọlọrun wa last

woos joor joor má lọ tesumole
egbodoku joor má tesumole
ah moni ko yàgò f’esu
ibi gíga autos má tesumole
ah moni ke yàgò f’esu
toby money joor má tesumole
ah moni ke yàgò f’esu
toochi lyrical má tesumole
ah moni ko yàgò f’esu
semiu 99 joor má tesumole
ah moni ke yàgò f’esu
asorogbayi joor má tesumole
ahan moni ke yàgò f’esu
nairamarley joor má tesumole
ah moni ke yàgò f’esu
guccimane-wa má tesumole
ah moni ko yàgò f’esu
rahman jago má tesumole
ah moni ke yàgò f’esu
ojora apasa má tesumole
ah moni ke yàgò f’esu
koba koba má tesumole joor
moni ko yàgò f’esu
eyin t’emi joor má tesumole
joor moni ke yàgò f’esu
jxyples joor má tesumole
joor moni ke yàgò f’esu
asorogbayi l’omo na é sha tiri
boshenlo baba eba
toby trice loveless
skrrobo skrrama
skrrobo skrrama

sman mix k!ller choi

letras aleatórias

MAIS ACESSADOS

Loading...