
letra de jerimoyah - wizka
[intro]
wur-uh-uh-uh-uh-uh-uh-uh
ee-ee-ee-ee-ee
(???)
wizka makun sko, oh-oh
yeah-eh-eh-eh
jerimoyah l’é
rimoyah l’èmèjè
(train wavy tk, mix it, baby)
oh, yeah-ay-ay-ay
jerimoyah l’é, jerimoyah l’èmèjè
jerimoyah l’émèjè, aw-l’émèjè
[chorus]
jerimoyah l’émèjè
ọbá t’òn gb’èdè k’èdè
ọbá tòh dári sànmón mèjè o
ọbá tiò ma l’áfiwè
é jé á sòh itàn jànmó mèji
l’óbá ló s’ódó wòli
k’òlè d’ólá, k’òlè nìyi
wòli s’óró f’ákókó
wi pè òwò nbó wá fún
sugbón láálá póju
f’òmó édá adam
wòli té siwáju ló
l’òbá s’óró fún ikèji
wì pè á r’òwò òjijì
l’òbá kò ájè mèji
l’ówó awón jànmó mèji
[post-chorus]
wì pè “é wì nté fé si
l’òwuró f’ójó mèjè
sugbón ranti ènìkèji
ọbá mi á má d’árá shá, rárá, kòs’éni bi
t’òbá d’èni, ò lè d’ólá, kò d’òdì fún ikèji
ọbá mi á má d’árá
[verse 1]
òju áyè
ò bá gbó nti time sóh
wá mó pè kò s’áláyè
ò nì ìbì t’èrè pór sunmó
ni ikèji át’ákókó
wòli má l’òn f’èdè fọh
wì pè “kòsi anybody
tá nkán t’òluwá wì
ákókó l’ólá pó ju
ò s’óró s’ájè pó ju
ikèjí d’éri ípónju
ò p’òshé ju ájè sọn
ilahi, óbá yì
má shèè wò mi
ábiámọ t’òlójá yì
mò d’èrò t’òri gáhin, ilahi
[refrain]
ọbá mi á má d’árá shá, rárá, kòs’éni bi (ye-ye)
t’òbá d’èni, ò lè d’ólá, kò d’òdì fún ikèji
ọbá mi á má d’árá shá, rárá, kòs’éni bi
t’òbá d’èni, ò lè d’ólá, kò d’òdì fún ikèji
ọbá mi á má d’árá shá, rárá, kòs’éni bi
ò lè d’ólá
(train wavy tk, mix it, baby)
kò d’òdì fún ikèji
letras aleatórias
- letra de love - haemolacriaa
- letra de 9 to 5 - bandar04
- letra de в голове хаос (my head is in chaos) - midix
- letra de stage dive - cassidy civet
- letra de with small we start - emily barker
- letra de my dark side - syko sam
- letra de dafür lohnt es sich zu leben - laith al-deen
- letra de inna yuh (raw) - vybz kartel
- letra de テイキング・オフ! (taking off!) - ゴダイゴ (godiego)
- letra de hinatanonioi - thursday's youth