letras.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

letra de táǹwá - the musical being

Loading...

ọjọ′ ńlọ ìgbá ńkọjá
ẹ’dá ń lògbà, ìgbá ń dẹwá
àlowónlé ń sáre ọlá oo

bọ′lanlé ń sáre owó oo
àrídunúu ń sukún w’ayọ’
iyọ′ ń wá′dún oyin
elédùà elédùà
mo ṣ’àduà wípé

ìràwọ′ mí átan
àlá ‘re áṣee, ah
ǹkán árọgbọ l′ọọ’dẹ′ wá
àgàn átọwọ’ àlàbosùn
àáoríre tàńwá

ìràwọ’ mí átan
àlá ′re áṣee
ǹkán árọgbọ l′ọọ’dẹ′ wá
àgàn átọwọ’ àlàbosùn
àáoríre tàńwá

ajé
jémi ní′pè
ojúmọ’ túntimọ′
jé n rítèmi ṣe
ọmọdé yii fẹ’ dàgbà
àgbá fẹ’ yígbà d′àpọ′n
‘lédùà mà ṣemí l′ádán
tó n f’ọ′san wò’ṣe ẹiyẹ ò
mà mà jẹ′ n ṣiṣẹ’ bí erin
kin jẹ”jẹ èlírí
mo gbóùn sókè
mo ṣ’àduà wípé

ìràwọ′ mí átan
àlá ′re áṣee
ǹkán árọgbọ l’ọọ′dẹ’ wá
àgàn átọwọ′ àlàbosùn
àáoríre tàńwá

ìràwọ’ mí átan
àlá ′re áṣee
ǹkán árọgbọ l’ọọ’dẹ′ wá
àgàn átọwọ′ àlàbosùn
àáoríre tàńwá

chant

ìràwọ’ mí átan
àlá ′re amáṣee (amin)
ǹkán árọgbọ l’ọọ′dẹ’ wá
àgàn átọwọ′ àlàbosùn
àáoríre tàńwá

ìràwọ’ mí átan
àlá ‘re áṣee
ǹkán árọgbọ l′ọọ′dẹ’ wá
àgàn átọwọ′ àlàbosùn
àáoríre tàńwá

letras aleatórias

MAIS ACESSADOS

Loading...