letras.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

letra de ayé le - pelumikiss

Loading...

intro:
oh nananana
kiss
pelumi on this one

verse:
to become a man
isn’t a days job
oluwa lo n bukun fun ni
lai se laalaa ah
baba bukun fun mi
ke mi maa tawona
baba bukun fun mi
ke mi maa se taraka

bridge:
ibi ti egbe mi ti n na owo
ke mi maa se na oju ni be oh
ibi egbe mi ti n soro
baba maa je n gbenu daake x2

chorus:
aah aye le
aye yii maa le (ayé àkámarà)
aaah aye le
aye yii maa le (ayé tó ń yaa ni láì lo camera) x2
hook:
na why i dey pray for blessings
blessings from above
ojo ibukun re
ko ro lemi lori

chorus:
aah aye le
aye yii maa le (ayé àkámarà)
aaah aye le
aye yii maa le (ayé tó ń yaa ni láì lo camera) x2

letras aleatórias

MAIS ACESSADOS

Loading...