
letra de shitan (open it all) o.i.a (2024 remastered version) - olawoleskinwhiz
(tias)
aah
okay
(see as you fine, see as you)
(purchase your tracks today)
ọmọ onídán, tan ná tan ná
so ló like wèrè
wón ma bá ẹ yàá kan lẹ′ oo
so ló like òṣì
wón ma bá ẹ ṣï tán
so ló like wèrè
wón ma bá ẹ yàá kan lẹ’ oo
so ló like òṣì
wón ma bá ẹ ṣï tán
ṣï tán
shi-ka-ta-no-va
shi-ka-ta-blan-ka oo
ṣï tán
shi-ka-ta-no-va
shi-ka-ta-blan-ka
ṣï tán
ṣï tán
ṣï tán
ṣï tán ooo
ṣï tán
ṣẹ ti rí wèrè oníjó
t′ólóun òní jó
t’óhun òbá rí igbó
ẹṣá majó mo ti tún
m’éléyìí k′alẹ′, ẹsá ma koo
ẹjẹ’ k′awé, olúwé máwé
tẹ’ tẹ′ mà, eeh
tẹ’ tẹ′ mà, kẹ’ kẹ’ mà
ṣẹtima:lizar, anar:mar
hoolaa
eeh-hyyii
ṣárà s′áwon tèmi, onídán
tan ná tan ná
iná wà, iná òṣí
wón ma tan ná
ajé o′ma rí na han
o’ti rí ′dán han(o’ti rí ′dán)
(tan ná tan ná) o’ti rí ′dán
wón ti gbé mi tràbayé
mo kọjá’ilé oo
wón ti gbé mi tràbayé ooh
ẹẹh, mo kọjá’ilé oo
hoolaa (jẹ kán mọ′n)
ọmọ oní ′dán, ẹmá pa’ná
(tan ná, tan ná, tan ná)
ẹmá pa′ná ògo mi, ògo mi
tin bá ti’ńkọ, k′ẹ ma ná mi
k’ẹ ma ná mi lówó
ẹmá pa′ná ògo mi, ògo mi
tin bá ti’ńkọ, k’ẹ ma ná mi
k′ẹ ma ná mi lówó
jẹ kán mọ′n
jẹ kán mọ’n, jẹ kán mọ′n
ọmọ oní ‘dán
tan ná tan ná
ẹmá pa′ná
ọmọ oní ‘dán
kòséré mọ′n
má gbà fún wọn
má gbà fún wọn o
letras aleatórias
- letra de bang bang bang - zakes bantwini
- letra de gang - yung trashi
- letra de hide and seek - halacg
- letra de transparent day (mono single mix) - the west coast pop art experimental band
- letra de hamilton medley - scottecs
- letra de this is hellfire 1 - bad boy (arabic)
- letra de it ain't tough - arabian prince
- letra de seperempat - gloomicide
- letra de own - tiwi_xo
- letra de dead and cold - her last sight