
letra de oil and gas - olamide
igbe, igbe, igbe-gbe-gbe, igbe
egbe, egbe-gbe-gbe, egbe
oga mi ẹnu gbẹ
ọ̀rẹ́ mi, ẹnu gbẹ
alaye, ẹnu gbẹ
walahi ẹnu gbẹ
owó wa lọwọ́ yín
ẹ jẹ ká báyín ná
epo wa lọwọ́ yín
ẹ jẹ ká báyín lá
ẹ le ná wó yẹn tàn
ẹ le l’epo yẹn tàn
ẹ le ná wó yẹn tàn
ẹ le l’epo yẹn tàn, eh
owó wa lọwọ́ yín
ẹ jẹ ká báyín ná
epo wa lọwọ́ yín
ẹ jẹ ká báyín lá
tony elumelu
wá ba mi jó sílú
femi otedola
è̩ ná mí ní dollar
asiwaju jagaban
ghana must go bag
oba elegushi
è̩ ná mí n kukushi
asiwaju tí bínú, yeh
wọn ni mi o mọ law
wọn ni kín ye gbé ghana must go
wá s’ilé àwọn ni bourdillon
omo, omo bullion van, yei
l’ọfí gbé wá fún mi, eh
dapo abiodun
o yí bíríbírí kàn mi
oga mi ẹnu gbẹ
ọ̀rẹ́ mi, ẹnu gbẹ
alaye, ẹnu gbẹ
walahi ẹnu gbẹ
owó wa lọwọ́ yín
ẹ jẹ ká báyín ná
epo wa lọwọ́ yín
ẹ jẹ ká báyín lá
ẹ le ná wó yẹn tàn
ẹ le l’epo yẹn tàn
ẹ le ná wó yẹn tàn
ẹ le l’epo yẹn tàn, eh
owó wa lọwọ́ yín
ẹ jẹ ká báyín ná
epo wa lọwọ́ yín
ẹ jẹ ká báyín lá
èyàn shina peller
my honourable
mc musiliu, eh
è̩yín lẹnu dá kú
ibd dende
áfún ni mà wo bẹ, yei
seyi tinubu
ògo lagos, oun l’ojú eko
o mọ̀ kunle poly
o mọ̀ 1805
o mọ̀ igbalode
gucci, gucci, èyàn hushpuppi
àwa lá ni lagos
(na we get this lagos)
ẹyín lẹ n’ìlé yín
(ẹyín lẹ ni lekki)
o mọ̀ dangote
cementi wọn lọ fí kọ ílé yín
ọmọ ase!
oga mi ẹnu gbẹ
ọ̀rẹ́ mi, ẹnu gbẹ
alaye, ẹnu gbẹ
walahi ẹnu gbẹ
owó wa lọwọ́ yín
ẹ jẹ ká báyín ná
epo wa lọwọ́ yín
ẹ jẹ ká báyín lá
ẹ le ná wó yẹn tàn
ẹ le l’epo yẹn tàn
ẹ le ná wó yẹn tàn
ẹ le l’epo yẹn tàn, eh
owó wa lọwọ́ yín
ẹ jẹ ká báyín ná
epo wa lọwọ́ yín
ẹ jẹ ká báyín lá
maintain bi t’olu
ko ye jó yahooze
t’o ba sanwo olu
wa ṣa sanwó toll gate, yei
(bring me my cooler, yo!)
maintain bi t’olu
ko ye jó yahooze
t’o ba sanwo olu
wa ṣa sanwó toll gate, yei
letras aleatórias
- letra de yŭ (pt. 2) - catching flies
- letra de 24/7 - kwaku
- letra de hello - certainly, sir
- letra de darkhall - mindless faith
- letra de tschernobyl ist in der nähe - aufbruch
- letra de kingdom of heaven - the poodles
- letra de take my rap…please - steve gordon & the kosher five
- letra de outskirts - small black
- letra de spiel mit dem feuer - saltatio mortis
- letra de sorry - alan doyle