
letra de fadaka club - musiliu haruna ishola
[verse 1]
l’aye n bi, musilimu babatunde
ṣe e r’egbe wọn bi?
egbe fadaka club, ṣe e r’egbe wọn bi?
alhaji riliwan mi adisa onifade, ọkọ fausatu, ọkọ farida, baba sodiq
olórí ẹgbẹ́
[chorus]
ṣe e r’egbe wọn bi? ṣe e r’egbe wọn bi?
eyin ti e ṣ’egbe yín jati-jati, ṣe e r’egbe wọn bi?
bó ṣe dára to
ṣe e r’egbe wọn bi?
wasiu adekunle (ṣe e r’egbe wọn bi?)
oko mojisola (ṣe e r’egbe wọn bi?)
oko lola (ṣe e r’egbe wọn bi?)
baba suraju mi (ṣe e r’egbe wọn bi?)
ṣe itọju governor general (ṣe e r’egbe wọn bi?)
sunday ọmọ ogunmokun mi (ṣe e r’egbe wọn bi?)
oko bisi baba sunday (ṣe e r’egbe wọn bi?)
prime minister (ṣe e r’egbe wọn bi?)
alhaji fasasi adesanya (ṣe e r’egbe wọn bi?)
oko serifat, baba rafiu mi (ṣe e r’egbe wọn bi?)
baba ramota mi (ṣe e r’egbe wọn bi?)
saka debo mi (ṣe e r’egbe wọn bi?)
oko bilikisu (ṣe e r’egbe wọn bi?)
tunji adeniran (ṣe e r’egbe wọn bi?)
isaja olomu ni ile (ṣe e r’egbe wọn bi?)
chief akogun onifade (ṣe e r’egbe wọn bi?)
oro ni (ṣe e r’egbe wọn bi?)
alhaji nojimu badiru mi (ṣe e r’egbe wọn bi?)
àwọn ni treasurer ègbé (ṣe e r’egbe wọn bi?)
oko risikat, baba rukayat mi ni (ṣe e r’egbe wọn bi?)
alhaji isa (ṣe e r’egbe wọn bi?)
sulaimon mi (ṣe e r’egbe wọn bi?)
isco director rentals (ṣe e r’egbe wọn bi?)
alhaji mi babatunde (ṣe e r’egbe wọn bi?)
babatunde la wa gboke yẹn (ṣe e r’egbe wọn bi?)
alhaji (ṣe e r’egbe wọn bi?)
owolabi ishola (ṣe e r’egbe wọn bi?)
oro ni (ṣe e r’egbe wọn bi?)
alhaji mi s.k mi (ṣe e r’egbe wọn bi?)
ọmọ osifade (ṣe e r’egbe wọn bi?)
oro ni (ṣe e r’egbe wọn bi?)
eyin ti e ṣ’egbe yín jati-jati, ṣe e r’egbe wọn bi?
[verse 2]
gbogbo fadaka lapapo
èmi a so fún wọn pé
life ota pe, dandan ni ko ye wa k’ale
t’awa ba tin lo s’oke, ta ba n lo s’oke, ka ma da ru fo
ibi to wun ota ni ki wọn gba lo, b’e ko sinu ere ko kan wa o
atago keyin aparo, òun oju n wa, òun l’oju mi a ri
[verse 3]
baba ẹgbẹ́ wọn l’otunba oyewole fasae, olórí oko pátápátá
ao b’ẹnikan di’te, ao b’ẹnikan binu
alo a dara fún wa o, abo a suwon f’egbe wa
ara iwájú o ṣe nkan, èrò ẹyin lo ṣe kisa, musiliu mi ishola
ẹni fe ko gbo n’ile orin, eni fe ko gbo n’ile orin o
t’eni o jo t’ana mo gb’orin d’ode o-ey
ẹni fe ko gbo n’ile orin, eni fe ko gbo n’ile orin o
t’eni o jo t’ana mo gb’orin d’ode o-ey
fadele director, ṣe otoju alhaji nurudeen, baálè agbede olosuko
e ṣe itọju foworori suraju mi
e ṣe itoju—
letras aleatórias
- letra de hillside - scuare
- letra de portion - eriq & jaypoppin
- letra de lov3 games - vulnrebel
- letra de último a sair - alcool club
- letra de mountains on top of buried stars - weird owl
- letra de opdatering - tj friz
- letra de what you wanted - louis la roche
- letra de creepy old man - azaleabs336
- letra de boop bop bing - leo black
- letra de đánh mất anh - dương thùy linh