letra de bí oba (remix) - mo'believe
[intro: mo’believe]
mobọ́ , mo’believe olumba lo shey beat
[chorus: mo’believe]
eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba
(it’s time for fun, you that sees dance and turn into a king)
ẹ̀ fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè ìlẹ̀ kẹ̀ ló ma jẹ ìyá l’álẹ́ ọ̀ ní
òní gángàn bá mi lùlù sí ìbèbè dí
(mr. gan-gan drummer, help me drum to the rhythm of the shaking waist bead)
torí
(because)
eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba
(it’s time for fun, you that sees dance and turn into a king)
ẹ̀ fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè
ẹ gbé rin sí orin mi
(sing along with me)
[verse 1: mo’ believe]
a mú ludùn ẹ má pè wá l’álágbe (2x)
(we are merry makers, don’t call us singing beggars;)
à wá ti dé pẹ̀ lú àtúndá eré (2x)
[bridge: mo’believe]
eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba
(it’s time for fun, you that sees dance and turn into a king)
ẹ̀ fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè
[verse 2: mo’believe] àgbàlagbà wá n sọ̀ pá nù
ọmọdé wá n sọ̀ ìtìjú nù t’abá ti bọ́ sí ágbo eré
egungun gbígbẹ ṣá ma n dìde
(dry bones rise again)
[chorus]
eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba
(it’s time for fun, you that sees dance and turn into a king)
ẹ̀ fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè ìlẹ̀ kẹ̀ ló ma jẹ ìyá l’álẹ́ ọ̀ ní
òní gángàn bá mi lùlù sí ìbèbè dí
( mr. gan-gan drummer, help me drum to the rhythm of the shaking waist bead)
torí
(because)
[bridge: mo’believe]
eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba
(it’s time for fun, you that sees dance and turn into a king)
ẹ̀ fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè
[verse 3: mo’believe]
a mú ludùn ẹ má pè wá l’álágbe
(we are merry makers, don’t call us singing beggars; bambiala)
a mú ludùn ẹ má pè wá l’álágbe
(we are merry makers, don’t call us singing beggars; bambiala)
òhun orí rán wa ṣé òun la wá ṣe
(we are doing what our destiny sent us to do)
ẹ̀ rí à tí pà gọ̀ , èró ti jade
orin ló sọ wá di ẹni ọba ń kí
( it is music that turned us to people the king greets)
orin ló sọ wá di ẹni ìjòyè ń kì
(it is music that turned us to people the chiefs praise)
orin ló sọ wá di ẹni ayé ń fẹ́
a mú ludùn ẹ má pè wá l’álágbe
(we are merry makers, don’t call us singing beggars; bambiala)
a mú ludùn ẹ má pè wá l’álágbe
(we are merry makers, don’t call us singing beggars; bambiala)
a mú ludùn ẹ má pè wá l’óní yẹ̀ yẹ
a mú ludùn ẹ má pè wá l’álágbe
(we are merry makers, don’t call us singing beggars; bambiala)
orin ló sọ wá di ẹni ayé ń fẹ́
[chorus: mo’believe]
eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba
(it’s time for fun, you that sees dance and turn into a king)
ẹ̀ fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè ìlẹ̀ kẹ̀ ló ma jẹ ìyá l’álẹ́ ọ̀ ní
òní gángàn bá mi lùlù sí ìbèbè dí
(mr. gan-gan drummer, help me drum to the rhythm of the shaking waist bead)
torí
(because)
eré dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ọba
(it’s time for fun, you that sees dance and turn into a king) ẹ̀ fẹ̀ dé, ọmọ a rí jó ṣe bí ìjòyè
ẹ gbé rin sí orin mi
(sing along with me)
[outro]
kòkòrò méjì bá pàdé ní ilé ijó
(when two dancers meet on the dsncing floor
eré wá di eré àríyá
(the fun becomes even double)
ìlù wá di ìlù àlùya
(the drummers beats his drum it almost tears)
ìlèkè wa di ohun àjójà
the dancer dances so much the waist bead tears)
orin wá d’orin àríyá
the song becomes a song of fun
t’óbá di orin oníwéré ko wéré
(when it comes to music, everybody sings their own)
t’óbá di orin oníwèrè ko wèrè
(when it comes to music, everybody sings their own)
t’óbá di orin àwa lóni òde òní
(when it comes to music, we own the melody of today)
àwá la n’ìlù ìlù àríyá
(we are drummers, the drummers of fun)
letras aleatórias
- letra de mama - skylight parade
- letra de your show - mateus de sá
- letra de tomo y bebo - yerba buena yb & eddy benjhy
- letra de the end of us - david posso
- letra de centipede - kaz moon
- letra de anlat - kurşun
- letra de if it wasn't you (from the voice of germany) - oliver henrich
- letra de hot blood - mizuki nana
- letra de pray - mizuki nana
- letra de la pharmacie - jul