letras.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

letra de ire - jët bøy

Loading...

intro
oooooooo
ire wa mi sile
ire ire wa mi sile o (jesu)
i stay on my knees and pray to him
make e shower his blessings

verse1
ki ire wa mi sile
ma je ko ma fi mi she yeye o
olugbala wa dariji wa oo (jesu)
ko orí mí tètè lá, k’orí ọlọlá máà pé ẹ rán níṣẹ̀ o
ẹ’dá mí tètè lá
ire wa mi sile
make i enemies nor see me
make i nor come down
ko orí mí tètè lá, k’orí ọlọlá máà pé ẹ rán níṣẹ̀ o
ẹ’dá mí tètè lá

bridge
ibukun ni mo fe
ayo ni fe
ire ni mo fe
ayo ni mo fe
ahan ahan
ki ire wa mi sile
maje ko ma fi mi she yeye oo
olugbala wa dariji wa oo (jesu)
ko orí mí tètè lá, k’orí ọlọlá máà pé ẹ rán níṣẹ̀ o
ẹ’dá mí tètè lá
mà ṣọ’pẹ
f’ore tó ṣé láyé mí, òpọ púpọ’
oooo

outro
its goldеn jët oo
fashionista
golden jët oo
baddest boy ooo ehhhh

ko orí mí tètè lá, k’orí ọlọlá máà pé ẹ rán níṣẹ̀ o
ẹ’dá mí tètè lá

jët baby eeeewuwuwu
jët bøy ooo

letras aleatórias

MAIS ACESSADOS

Loading...