letras.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

letra de oba nla - iyabo idowu

Loading...

oba nla tenikan ole daduro,oba nla tenikan ole dilowo, alase laye alase lorun o, oba nla tenikan ole daduro,oba nla tenikan ole dilowo
oba nla
chorus:oba nla tenikan ole daduro, oba nla la la
oba nla tenikan ole dilowo,iwo lalase laye
alase laye, alase lorun o oba nla tenikan ole daduro, mio roba biire oba nla tenikan ole dilowo
iwo loba nla oba to ju gbogbo oba lo, iwo loba nla torun oun aye n wari fun,ogbe nu orun pase, ogbe nu orun sogo,oba nla tenikan ole daduro oba nlanla tenikan ole dilowo
iwo loba nla oba to ju gbogbo oba lo,oju gbogbo oba lo,iwo loba nla torun oun aye nwari fun,won wari fun o,ogbe nu orun pase ogbe nu orun sogo, onpase lori ite onsogo ninu olanla,oba nla tenikan ole daduro,oba nla tenikan olе dilowo
chorus:oba nla…oba nla tenikan ole daduro,oba tawujale nwari fun oba toni ifе nkesi,oba tolo kanrin kese,alase laye alase lorun o,oba nlanla tenikan ole daduro oba nla tenikan ole dilowo
kabiesire re o oba toto gbani,iwo loto gbani,kabiesi re oba ton gbadobale oba, oba aye ama je dun saa ati akoko kan ninu aye, amo oluwa njoba olanla lowo laso,ayeraye ni joba re de iran diran gbogbo,oba nla oba ton foba je ooo,oba nla toba aye nwari fun, kabiesi olorun
chorus:oba nla tenikan ole daduro,tenikan ole di lowo o,oba nla tenikan ole di lowo,oba toti un joba koba aye oto ma joba, alase laye alase lorun o,be lon pase ninu orun,oba nla tenikan ole daduro mogbo suba fun o, oba nla tenikan ole dilowo
interlude
olo kanrin kese oluda iku tiku ole pa,gigun lailopin janran janran fenfe fenfe,okere ogba nu eniyan otobi titi orun ogba ooo,ofaye se itise ase orun ase aye, koseni fi o joba ede seni lero oloye,ayeraye ni ijoba re de irandiran gbogbo,obanla oba ton foba je ooo,oba nla ti gbogbo aye nwari fun.ese kabiesiooo
chorus: oba nla tenikan ole daduro,mose kabiesire oba,oba nla tenikan ole dilowo,oba ton joba lori aye ati ekun re,alase laye alase lorun o,onjoba lati orun de orun aye de aye,oba nla tenikan ole daduro, koseni le di o lowo oo,oba nla tenikan ole dilowo
osuba reee baba ooo,osuba re oo baba
osuba re ree baba o,osuba re re to baba olori aye iba re mose,mogbo suba fun o o baba,emi gbosu ba fun o o baba
mokan sara,sara re ree baba o sara re re o baba,e ban kan sara ,sara re re baba o,sara re re o baba,olori aye iba re mose mogbo suba fun oo baba, iwo loni kokoro dafidi lowo oun tobati koseni lesi lailai, mogbo suba fun o o baba,oba to fi gbogbo ara se kiki ogo alade ogo oni ite ogo, mogbo suba fun o o baba,eni oba binu si koseni le yonu sir,eni oba dalare koseni le da lebi o,mogbo suba fun o o baba,oba aye amaa waja sugbon olorun orun laiku aisa aidibaje o, mogbo suba fun o o baba

letras aleatórias

MAIS ACESSADOS

Loading...