
letra de colose - islambo
[intro: islambo]
mo n lo e pe mi pada
oba idán ni e pe ni peller
agba ni methuselah
blow my trumpet and vuvuzela
[verse 1: islambo]
zubu zubu zaba zibo
sho b’owo de k’ama nìṣó (slowdown)
patiently sabali
k’eni binu o mu gamale
ohùn owo mi o to, ma naga
eyin ṣi n fi gongo fa
aiye n yi bi jangilova
ore, pariwo oṣo níwọ̀n ba
[chorus: islambo]
ko si ninu iwe colose
pé won ṣi ma fa colos
lo mu ekelebe smile bori ote
when i’m high ale pade loke
talo wa ni agility mi o yi to?
to lon f’ẹ̀jẹ̀ we pito
f’ẹnu ja o n ṣe casamigos
gba coin, gba raba, wo jalingo
ko si ninu iwe colose
pe won ṣi ma fa colos, hmm
[verse 2: citiboi]
iwo n ṣ’ọkọ̀ rebe
nibi tí awon kan ti n fo fèrèsé
jo, ba mi gbo orin dáfídì
mio tọrọ ìdáríjì
deren ren o darlington
ile aye ni vaniti, oṣe
house party wọn play house music
log drum, amapiano, extra sheet
wọn fe tu bii àṣírí (àṣírí)
a n miri si amiri yin
yòó dara fún o
ọmọ igbala ṣe hallelu (hallelu)
nibiti a ti n mezebu (mezebu)
pàdé mi l’òkè angelu (angelu)
house party wọn play house music
log drum, amapiano, extra sheet
won fe tu bii àṣírí (àṣírí)
a n miri si amiri yin
[chorus: islambo]
ko si ninu iwe colose
pé won ṣi ma fa colos
lo mu ekelebe smile bori ote
when i’m high ale pade loke
talo wa ni agility mi o yi to?
to lon f’ẹ̀jẹ̀ we pito
f’ẹnu ja o n ṣe casamigos
gba coin, gba raba, wo jalingo
(níbo?)
[outro]
beat from the city
letras aleatórias
- letra de (ex) ex - stray kids
- letra de nitasubiri - jux
- letra de monday morning - kay bridges
- letra de nogomet - pips, chips & videoclips
- letra de the gamera song (part 1) - mystery science theater 3000
- letra de zeze (birdy records remix) - birdy records
- letra de sadneess thru' weakness - ascraeus
- letra de future, past, present - a letter home
- letra de lazer beam - value
- letra de deep red - dani lee pearce