letra de ahan - ibrahim maalouf & angélique kidjo
kossi, kpashan kan, kossi shèkèshèkè kan
kossi igban kan, kossi shèkèshèkè kan
kossi, kpashan kan, kossi shèkèshèkè kan
kossi igban kan, kossi shèkèshèkè kan
e sọ fun mi solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
e sọ fun mi solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
eyin nin ọba, enin oba jerusalemu
alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
ni waju yin, emi ni obinrin dudu ti è kpatchè foun
e sọ fun mi solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
e sọ fun mi solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
eyin ti èsso m’kpé moji omi orisun yin
alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
shugbon m’bo ni agbara yin kouro?
ninou owo wo lè n’mou ida yin o?
shugbon m’bo l’owa lara yin oooo
shugbon m’bo ni agbara yin kouro?
kabi èssè yin to n’sare lo si ogun
shugbon te ni ailopin agbara léri eniyan
e sọ fun mi solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
e sọ fun mi solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
eyin nin ọba, enin oba jerusalemu
alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
ni waju yin, emi ni obinrin dudu ti è kpatchè foun
e sọ fun mi solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
e sọ fun mi solomoni, ohun gbogbo lo gbé wa lọtọ nin sin
alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
emi ti èsso m’kpé moji omi orisun yin
alagbara ọkunrin, ọkunrin funfun
shugbon m’bo ni agbara yin kouro?
ninou owo wo lè n’mou ida yin o?
shugbon m’bo l’owa lara yin oooo
shugbon m’bo ni agbara yin kouro?
kabi èssè yin to n’sare lo si ogun
shugbon te ni ailopin agbara léri eniyan
kossi, kpashan kan, kossi shèkèshèkè kan
kossi igban kan, kossi shèkèshèkè kan
kossi, kpashan kan, kossi shèkèshèkè kan
kossi igban kan, kossi shèkèshèkè kan
letras aleatórias
- letra de moonless - julie byrne
- letra de summer in the rain - blk odyssy
- letra de sulle hills - diego [ita]
- letra de bout it bout it - lowkeemtl
- letra de real selfish - reazo
- letra de funeral - lucifer jones
- letra de bowl cut - killua the pilgrim
- letra de addy outage - rocstarpatty
- letra de my perfect tragedy - skywind
- letra de c.p. company (feat. star boy and dom corleo) - ng1max