letra de way up - dreez maliq, bhadboi oml
intro
ire wọle o, baba, mo wa f’ọpẹ fun ọ
mo sun layọ, mo ji layọ, mo wa yin ọ logo
dide mo de o, baba mimọ o, mo wa f’ọpẹ fun ọ
mo sun layọ, mo ji layọ, mo wa yin ọ logo
verse
bi mo ṣe n jade lọ, baba, ṣọ mi ninu aye
bi mo ṣe n jade lọ, baba, baba, ma jẹ n tan ‘nu aye
protect all my friends, and my family, yeah
b’araiye gbogun wa, you go set me free
ma ṣe mi l’oniṣẹ, ori jẹ ki n ye
’cause you are merciful, oh lord
chorus
i am going up
up is the only way (eh-eh-eh-eh)
never going down
down with my enemies
i am going up
up is the only way (eh-eh-eh-eh)
never going down, down, down, down with my enemies, oh-oh
verse
if e no be god, i no fit stand tall
aye fẹ de’kisa fun ọmọ alaṣọ ọ
so many battles’ wey i fight o
but i’m still here, mo wa d’ọmọ t’ọn sọ
verse
dide mo de o, baba, mo wa f’ọpẹ fun ẹ
jiji mo ji o daadaa
shine your mercy, lord, ayy
ara ọmọ o ya o, baba, oh
i’m sick of envy, lord
verse
ayy, dide mo de o, baba mimọ, oh
mo kọ lọ n daro lọ, oh yeah
oh my brother, oh my brother
tori kan ba san o aran gba
aba l’ọn daa o, maa j’ọba
oju ẹ mo n wo, jọọ, ma lọ ka, eh-eh-eh, ọmọ-ọla
hook
ire wọle o, baba, mo wa f’ọpẹ fun ọ
mo sun layọ, mo ji layọ, mo wa yin ọ logo
dide mo de o, baba mimọ, maa f’ọpẹ fun ọ-ọ
mo sun layọ, mo ji layọ, mo wa yin ọ logo
bridge
ara ọmọ o ya o, baba (alubarika loju)
i’m sick of envy, lord (k’oluwa fere si o)
dide mo de si ẹ lọrùn (ọmọ-ọla)
mo kọ lọ n daro lọ ọ-ọ
outro
(kaycekeys on the beats)
(maliq)
letras aleatórias
- letra de pop - katalinoff
- letra de vai vaqueiro - michele andrade & ramon e randinho
- letra de gift of love - nora aunor
- letra de don't come back - drxvegitoz
- letra de estremece terra - trashxrl
- letra de degel - דגל - rockfour - רוקפור
- letra de флоуwow (flowwow) - m1kron
- letra de pulling weeds - kasey tyndall
- letra de miss u.mp3 - fallen777angel
- letra de the cook has horns - chef nav