
letra de edumare - dainywest
verse
mélòó mo fé sáláyé ọ’
you no fi block my way oh
bàbá lóòkè sá lọ sọ ẹ’mí ò!
òrì mí já fún ẹmí ò!
verse
mo tún àbẹ’lá ni
fi gbàdúrà ní
káràyé má tà épò sálá mi
baba gbọ’ tèmi ó
káràyé má sọ pé òpárí o!
verse
èmi ìdòní gòngón, mi ò gbọ’ kònkòn!
bullion van fé fi kò owó lọ
i dey face my fears, and me i know care
look on god, baba lift my heads
verse
cause me i no fi give up
and this life dé rì bá kòn
káràyé má lọ rí mi tòn
bàbá jọ’, kó má sọ mí lọ
má jẹ’ kín jàbọ’ oo
chorus
èdùmàrè, cover me o
baba, cover me o
má jẹ’ kó bà mí o
olúwa, cover me oh oo
chorus
hmmm, baba, cover me oo
oh oo
èdùmàrè, cover me
chorus
olúwa, cover me oo
oh oo
má jẹ’ kó bà mí oo
bridge
me i no fi fo fo
i’m a fit gangster fighting kung fu
an i put my soul and life on god
and me go vibes till kingdom come
verse
kílọ’ fẹ’ sọ’, àní kí ló fẹ’ sọ’
wọ’n ti bẹ’bọ’ wòlé rí kọ’n kọ’n
àlá kọ’bà kò ní molẹ’ wá
fún mi rissler, bá mi wẹ’ cana
verse
ẹyin tó láyé, ẹ’ dúró tì mí o
kó má ṣe pa fítílà mí o
kálànú mi, kówá mí rere o
ó ṣúre pé mo máà kọ’rẹ’dé, baba bámi se
verse
mọ’rànú gbà lọ’wọ’ baba
mó wá jùbà fún olúwa wa
bí mo ṣe lọ, bí mo ṣe bò
máa só mí lọ, máa jẹ’rí dé n’ó
chorus
èdùmàrè, cover me o
baba, cover me o
má jẹ’ kó bà mí o
olúwa, cover me oh oo
chorus
hmmm, baba, cover me oo
oh oo
èdùmàrè, cover me
chorus
olúwa, cover me oo
oh oo
má jẹ’ kó bà mí oo
letras aleatórias
- letra de depression kid - slowbarry
- letra de toi & moi - ilume
- letra de crayon - sorane (空音)
- letra de count me in - d.e.a.n x
- letra de polar night - mildrage
- letra de gorilla - trap king (dz)
- letra de the thrill - wayne snow
- letra de allo toso - stoixeiothetis (grc)
- letra de surfing the universe - cheekbonez
- letra de twenty times time - lazytown