letras.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

letra de se bo'timo - brymo

Loading...

ij-pa o n’ibi ti o n lo
kele kele, o n rin, o n lo
araye n yimu, o n lo
ero wa, ero lo, o n lo

ko gba agidi
o ro bi a, b, d
ti o ba koju mo tie
ti mo koju mo temi

bi a ba fi eyin si owo otun
ki a feyin sowo osi
ki awa f’eyin rin lati ahin titi de iseyin
eni ma yini, a yini
eni o ni yini, ko ni yini

se bo’timo ore
se bo’timo ore mi
se bo’timo mama
se bo’timo baba mi

won n tan e
dakun ye maa tan ara re
t’ire n t’ire
ye ma ko ara re
bi o ba sare, bo subu
iwo lo lara re
b’ole, b’oro
ore, ma paara ire
ko gba agidi
o ro bi a, b, d
ti o ba koju mo tie
ti mo koju mo temi

bi a ba fi eyin si owo otun
ki a feyin sowo osi
ki awa f’eyin rin lati ahin titi de iseyin
eni ma yini, a yini
eni o ni yini, ko ni yini

se bo’timo ore
se bo’timo ore mi
se bo’timo mama
se bo’timo baba mi

letras aleatórias

MAIS ACESSADOS

Loading...