letra de adura - big whale
ok eja nla… big whale… je oo moor jẹ ooo moor don pizzle je oo moor jẹ oo moor … je oo moor jẹ oo moor
chorus
gba ádùrá mi baba baba loke, gba adura mi baba baba loke eeee.. ko omo elegun pada wa jẹran kó mọ alakisa pada wa wọr asho k’emi na paradà kin dolowo…
gba ádùrá mi baba baba
loke, gba adura mi baba baba loke eeee.. ko omo elegun pada wa jẹran kó mọ alakisa pada wa wọr asho k’emi na paradà kin dolowo..
verse 1
adura mi àagbà oo, ádùrá rẹ àgbà oo ọna mi maala oo ma ri batishe oooo… adura mi agba óò àgba oo agbá oo ádùrá rẹ àgbà oo agbá oo agbá… isu paradà odi iyán àgbàdo paradà oo deko mò fé paradà dolowo mo fé paradà dì olola mo fẹ paradà dì olókìkí mo fẹ paradà dì olókìkí láàyè ti mo wà yí oo… tori ọdọdún là ri orogbó ọdọdún là ri awùsá ọdọọdún lá ri omo òbí lórí ìgbà ọdọdún là ri orógbó oo dun la rawusa ọdọdún là r’omo obi loori ìgbà
chorus
gba ádùrá mi baba baba loke, gba adura mi baba baba loke eeee.. ko omo elegun pada wa jẹran kó mọ alakisa pada wa wọr asho k’emi na paradà kin dolowo…
verse 2
baba l’oke bless me na k’ẹmi lọwọ bless mi na k’ẹmi lọla bless mi na k’ẹmi de’bẹ k’ẹmi omo ibajẹ rí ona loor ee assure pe ma de’be you want to blow no be by label add more good more money for my life oo.. oromi ọmaja sí rẹ wani òma ja si ayọ oma já ṣí okun un lеt money follow me oo ibi ti ma de ma dе’be ikan ti mò fẹ ma ribe baba l’oke jé kaye mi dáa oo
chorus
gba ádùrá mi baba baba loke, gba adura mi baba baba loke eeee.. ko omo elegun pada wa jẹran kó mọ alakisa pada wa wọr asho k’emi na paradà kin dolowo…
gba ádùrá mi baba baba loke, gba adura mi baba baba loke eeee.. ko omo elegun pada wa jẹran kó mọ alakisa pada wa wọr asho k’emi na paradà kin dolowo…
outro with low sound
iṣu paradà odi iyán àgbàdo paradà odi eko mo fé paradà dì olówó no fé paradà dì olola (in this life i don’t wanna die young i need money) mo fé parada dé ibí gíga parada dé ibeyen ahn wù ahn wù ahn omo ibajẹ
letras aleatórias
- letra de chimpanzee - matt mcnish
- letra de gentlemen - väike
- letra de slave of heaven - doom (jpn)
- letra de natale - dolcedormire
- letra de 6 days till christmas - liz elias
- letra de tempesta - pathos
- letra de harshest critic - allison ponthier
- letra de way you are - rick snow
- letra de rapina - baby gang
- letra de closed casket - steven_outlawz_king