letra de mu'ra ode - beautiful nubia and the roots renaissance band
Loading...
igbeyin lo ju o, k’o mo
sebi ‘bere, iyen ki s’onise
ka f’ara s’ise o to jare,
ka f’ogbon si o, pelu suru
a ti ru’bo oju, a s’oro didun, f’eni t’o nworan o,
ka ma ma ko’se
a ti d’omi siwaju, ka le te’le tutu
ka ma se r’oun ti o koja emi wa
sa ma gb’ese lokankan olufe
ojo ti da wayi, ko s’abata l’ona
fu’rugbin s’apa otun ati s’owo osi
oni ojo ibukun, ero ni gbeyin iji
ya mu’ra ode, olufe
ko s’oun t’o nbo wa to le si o ni’po
jijo re s’egbe otun ati s’apa osi
oni ojo idunnu, ojo ni gbeyin erun
igboya ni o gbe wa, k’o mo
oniberu, awon yen o ni le duro
ka be olu-aje o to jare
ka s’ise lo ju, lai s’awawi
a ti ru’bo oju…
letras aleatórias
- letra de splice & dice - vintage culture
- letra de no song today just pain. - lil boom
- letra de go - senyss
- letra de you're diabetic - taco vomit
- letra de fujiko - grosz
- letra de stressed out - georges cinq
- letra de lost in a hopeless place - alicewell
- letra de small talk - tohoshinki
- letra de vou seguir em frente - gutierrez
- letra de smash* - cookiez