letras.top
a b c d e f g h i j k l m n o p q r s t u v w x y z 0 1 2 3 4 5 6 7 8 9 #

letra de my father my father - barry jhay

Loading...

oh-oh-ohhh-oh-oh-ohhh-
oh-oh-ohhh-oh-oh-ohhh, ye-ye
(mad-madaroad)

oh-oh-ohhh-yea-yea-ohhh-
ye-ye, ye

say, i don′t force it
i just let the spirit lead, ’cause i know
yes, i know you are with me all the way

my father, my father, ọlọrun ti ko kí ń yipò padà
ọrọ ayé mí ọwọ ẹ lowa, ìwọ nìkan ní mọ gbẹkẹmilẹ o, ah (ẹru ògo rẹ ńbámí)
ẹlẹwa ògo (hm), àdàbà mímọ, jọwọ, bale mí o oh-ohh (emi ọmọ rẹ ree)
mo tún dúró síwájú rẹ bí mo ṣe má ńṣe
ẹmí-mímọ, jọwọ, wá gbé mí fo oo
mo fẹ ga nínú wọn (gbà mí gbọ)
má ṣe gbàrà lewọn, má ṣe gbẹkẹlẹ′nìyàn
ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, ye, re o
má ṣe gbàrà lewọn, dákun, má ṣe gbẹkelẹ’nìyàn
ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, yeah-oh

ìrìn yí mọọ, má lọ lofo, ní mo ṣe d’ẹsẹ′ ọlọ́run mí mú o, uh
(ní mo ṣe gbà ọlọ́run mí mú ṣinṣin)
bí olùwà ṣe ń sọla ìyẹn nínú ọlá àt′ayo
bẹ ní yí o tún ṣògo, ohh, ọlọrun mí ògo

my father, my father, ọlọrun ti ko kí ń yipò padà
ọrọ ayé mí ọwọ ẹ lowa, ìwọ nìkan ní mọ gbẹkẹmilẹ o, ah (ẹru ògo rẹ ńbámí)
ẹlẹwa ògo (hm), àdàbà mímọ, jọwọ, bale mí o oh-ohh (emi ọmọ rẹ ree)
mo tún dúró síwájú rẹ bí mo ṣe má ńṣe
ẹmí-mímọ, jọwọ, wá gbé mí fo oo
mo fẹ ga nínú wọn (gbà mí gbọ)
má ṣe gbàrà lewọn, má ṣe gbẹkẹlẹ’nìyàn
ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, ye, re o
má ṣe gbàrà lewọn, dákun, má ṣe gbẹkelẹ′nìyàn
ìgbẹ́kẹ̀lẹ ènìyàn asán bansa, yeah-oh

(sunshine on the mix)

letras aleatórias

MAIS ACESSADOS

Loading...