
letra de military - asake
[verse 1]
uh
àwọn ló ń l’ẹ́nu
wọ́n kò ń máa sọ lò
tí ò bá ti affẹ́ct bank mi, kó máa sọ̀rọ̀
making money, mo wà focused
military régime, show love
la mèdàl ló ń ọmọ tó ń sọ
ó kan máa sáré, sáré, sáré, o ò le bá a bó ti lọ
èmi kò ní ọlọ́run ni, ọlọ́run ló dá a mi
òyìnbó kòrò l’ẹ́nu mi
[chorus]
for my set, who get money pass me?
kò má sì
èmi kàn like low-key
achievement all over the world, wọ́n mọ̀
stubborn, you fit do am? ó yá, go front
make i stop, make i chill
i fit dey go from now till early mó̩-mó̩
ọmọ ọlọ́run
mi ò gbọ́dọ̀ máa sọ̀rọ̀ too much
pause if you must, but don’t stop
[segue]
shout out olamide badoo
ìdàn
[verse 2]
mo lè drop album l’ọ̀lá tí inú bá bì mi
zero tracklist, mo lè gbé wọn sáré ni
mo lè ní kí wọ́n lọ gba wọ́n lẹ́tí ni, but máa stop it torí pé mo ṣiṣẹ́ dé bí ni
talk your sh-t, mo mọ̀ pé o máa ń kó bà mi
ọmọ, f-ck that sh-t, kúrò níbí ni
ṣé àgídí ni?
bọ̀bọ̀, bọ̀bọ̀, má gb’ọ̀wọ́ mi
alákọ̀bá jìná s’ọ̀dọ̀ mi
[chorus]
for my set, who get money pass me?
kò má sì
èmi kàn like low-key
achievement all over the world, wọ́n mọ̀
stubborn, you fit do am? ó yá, go front
make i stop, make i chill
i fit dey go from now till early mó̩-mó̩
ọmọ ọlọ́run
mi ò gbọ́dọ̀ máa sọ̀rọ̀ too much
pause if you must, but don’t stop
letras aleatórias
- letra de the information - madam adam
- letra de margiela - sagetwofour
- letra de morning lights - moderntears'
- letra de yo sé - ñejo
- letra de parliaments - thank you, i'm sorry
- letra de she stole my heart - heaven (au)
- letra de habit - glori wilder
- letra de nice - amindi
- letra de all we need - dopesmoothies
- letra de always wanted - maximilian (uk)