letra de oré - asa (asha)
Loading...
ma ya lé mi iwo orè atojubo onilé
ma ya lé mi iwo orè agbok’oloko
ma ya lé mi awon orè adugbo
ma ya lé mi ma ya lé k’omo
orè ti mo mu bi aburo
orè, orè ti mo sé daara dara
orè ti mo fi nu hun
owa daami o tumi sita
odabi oro ano
bi oro ano
don’t come to my house,
iwo orè éké adugbo
don’t come to my house,
iwo orè adaléru
maya lé mi, orè kofeniferé
maya lé mio maya lé rara
isè ni mo wa lojo yi o
oko t’o fèmi si lè
ko ku lo wa sè sé
la won mejéji, won bèrè isé kusé
won wuma omodé, won sé wun won
odabi oro ano
bi oro ano
ewa wo ija lo jo yen
ewa wo éro ton tu ta
ewa wo ara lojo yen
ejé rée ni le
ma ya le mi toro iyo
ma ya le mi toro ata
ma ya mi le rara
isé ku sé kun owo rè
i don’t want to see you no more
letras aleatórias
- letra de life (freestyle) - thomas coleman
- letra de na siebie liczę - bob one x bas tajpan
- letra de молодые и злые (young and evil) - триада (triada)
- letra de blomst - isak shorty
- letra de minotaur forgiving minos - moonface
- letra de invictus - moses guest
- letra de un mundo raro - rocío dúrcal
- letra de dumb luck - los campesinos!
- letra de sotheby's of the dead - nautics
- letra de la vita e poi - julie zenatti