letra de gbogbo e ni - apostle ruben agboola jp
gbọ′gbọ’ ẹni tó f′ẹrin bá mi ja
gbọ’gbọ’ ẹni tó f′ẹrin dà mí lóró
igbe rárà lára ńké wọle
jékọ́ sunkún jáde láyé
gbọ′gbọ’ ẹni tó f′ẹrin bá mi ja
gbọ’gbọ′ ẹni tó f’ẹrin dà mí lóró
igbe rárà lára ńké wọle
jékọ́ sunkún jáde láyé
ìno ni ó jọ ọ′tá ilé bàbá
ìno ni ó jọ ọ’tá ilé màmá tóbí mi (ìno ni ó jọ ọ’tá ilé màmá tóbí mi)
nínú ayé
ẹnì tó f′ẹrin bá mi jà (ohhhh, ohhh, ohh, oh)
awọn ti wọn f′ẹrin dá mi lóró
igbe rárà lára ké wọlé (ahhhh lára ké wọlé)
jẹ’kó sunkún jáde láyé
gbọ′gbọ’ ẹni tó f′ẹrin bá mi ja
gbọ’gbọ′ ẹni tó f’ẹrin dà mí lóró
igbe rárà lára ńké wọle
jékọ́ sunkún jáde láyé
ó ṣe bí ọrẹ ṣé ibì, ọ’tá mi lọ jẹ
ó ṣe bí ènìyàn pàtàkì ó ní mi lara
ẹni tó f′ẹrin bá mi ja
jẹkó sunkún jáde láyé
gbọ′gbọ’ ẹni tó f′ẹrin bá mi ja
gbọ’gbọ′ ẹni tó f’ẹrin dà mí lóró
igbe rárà lára ńké wọle
jékọ́ sunkún jáde láyé
iwó ni ó bá mi lépa
b′ọ’tá mi bá fẹẹ yo kondo
iwó ni ó bá mi lépa
b’ọ′tá mi bá fẹẹ yo kondo
ọlọ́run máà ṣe gbà fún wọn
awọn arògó bo gó je
iwó ni ó bá mi lépa
b′ọ’tá mi bá fẹẹ yo kondo
iwó ni ó bá mi lépa
b′ọ’tá mi bá fẹẹ yo kondo
ọlọ́run máà ṣe gbà fún wọn
awọn arògó bo gó je
ọlọ́run mi
gbọ′gbọ’ ẹni tó f′ẹrin bá mi ja
gbọ’gbọ’ ẹni tó f′ẹrin dà mí lóró
igbe rárà lára ńké wọlé (ahhhh lára ké wọle)
jékọ́ sunkún jáde láyé
gbọ′gbọ’ ẹni tó f′ẹrin bá mi ja
gbọ’gbọ′ ẹni tó f’ẹrin dà mí lóró
igbe rárà lára ńké wọlé
jékọ́ sunkún jáde láyé
jékọ́ sunkún jáde láyé (jékọ́ sunkún jáde láyé)
jékọ́ sunkún jáde láyé (jékọ́ sunkún jáde láyé)
àní ní lara ilẹ′ bàbá mi yẹn
jẹkó sunkún jáde láyé (jékọ́ sunkún jáde láyé)
letras aleatórias
- letra de zazoo zehh - poco lee
- letra de крылья (wings) - sorrowyth
- letra de ego is the enemy - william truelove
- letra de $inners grave - am no pm
- letra de durny - koniec świata
- letra de зависимость (addiction) - vulpes vult!
- letra de jadą rowery - epis x intruz
- letra de slow nights - besomorph
- letra de kraj mene - erik miko
- letra de little roach - plumes