
letra de bahia - angelique kidjo
aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé
aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè
ouidah ni ilé ti bahia
ti émin mon wa, ri yin lénin o
bahia, bahia, bahia, bahia, bahia, bahia
ilé ti babawa djinan, awa fè lolé
bahia ilou ti awa lenin, okpè gan si ilé
ogun ti awon agbalagba, shé kalè foun wa o
logbé wa lo si bahia, gbé gbogbowa kpo
bahia, bahia, bahia, bahia, bahia, bahia
odjo ikadé wa m’bowa o, ti ale rira wa
ewa ka moura foun odjo yin, ninou oyaya
oluwa foun wa ni ayé, edjè ka du kpè
bahia kpa gbogbowa kpo, iréti wa lonan
aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé
aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè
ouidah ni ilé ti bahia
ti émin mon wa, ri yin lénin o
oré ifé ayé ilé, oré ifé ayé ilé…
aburo, orè ni gbogbowa, ewa ka lolé
aburo, ibi kan ni wao, kamura si ifè
ouidah ni ilé ti bahia
ti émin mon wa, ri yin lénin o
oré ifé ayé ilé, oré ifé ayé ilé…
———————————————————
translation:
bahia is so far from motherland
but the spirit is still alive
one day we’ll come together
i want to cross that bridge
it leads from ouidah to bahia
thanks to sabryna
letras aleatórias
- letra de 2020 vision - j.simplicity
- letra de dum dumb - mook
- letra de in the middle - townz mega
- letra de apple tree (acoustic) - aurora
- letra de old story - television recorder
- letra de shots (the young professionals remix) - imagine dragons
- letra de surfa vågen - papi santana
- letra de sing your song - hannah jaye and the hideaways
- letra de chuvas de cabo verde - sérgio godinho
- letra de район (borough) - жека расту (zheka rastu)