letra de ogo - aduke gold
sebi nitori ogo ni o
nitori ogo ni,
ohun ti oju ologo ba ri o
nitori ogo ni
sebi nitori ogo ni ke
nitori ogo ni,
ohun ti oju ologo ba ri oooo
nitori ogo ni
aimoye ogun to ma bori
ka to f’oruko olorun pon e le
aimoye iji to ma ja
ka to pe o la lagbara
aimoye ina ta ma la koja
ki wura aiye eni le tan yirinyirin
aimoye abukun ta ma kan
k’aponle to de ba m’ologo
a da bi, pe olorun o si lori ite mo
a wa jobi pe, majemu o si fun onigbagbo mo
igba to ba le,
to da bi wípé ko si ireti mo
ogo lo fe de yen o
iranlowo bo wa,
iyanu ti fe sele
orun ire ti fe si
omije oni je o ri
sebi nitori ogo ni o
nitori ogo ni,
ohun ti o mu olododo bu s’igbe o
nitori ogo ni
sebi nitori ogo ni o,
nitori ogo ni
ohun ti oju ologo ba ri laye o
nitori ogo ni
a se olorun mo si
a se olorun da mi mo
gbogbo ohun ti mo la koja laye
fun ogo oluwa ni
a se olorun mo si
a se olorun da mi mo
gbogbo ohun ti mo la koja laye
fun ogo oluwa ni
olorun ri e o,
olorun ri e o
b’ose jade lo wuro to pade lale
olorun ri e o…
olorun ri e o,
olorun ri e o
awon to ro e pín tóní o le se rere laye
olorun ri o
a da bi, pe olorun osi lori ite mo
a wa jobi pe, majemu osi fun onigbagbo mo. o
igba to ba le, to da bi wípé ko si ireti mo
ogo lo fe de yen
iranlowo bo wa,
iyanu ti fe sele
orun ire ti fe si
omije oni je ori
sebi nitori ogo ni o(nitori ogo ni)
nitori ogo ni,
ohun ti oju ologo ba ri o(oun to mu e sukun)
nitori ogo ni (nitori e)
sebi nitori ogo ni o(b’ose nri f’ologo ni yen,ma roju e)
nitori ogo ni
ohun t’oju ologo ba ri o(ohun ti
oju ologo ba ri o, e so fun, sa ma roju)
nitori ogo ni (sa ma roju)
a se olorun mo si (olo. run mo si)
a se olorun da mi mo (beni olorun da e mo)
gbogbo ohun ti mo la koja laye
(ka to loyun e lo jo si, lo ti gbe e so kan)
fun ogo oluwa ni(o mo ni pa re)
a se olorun mo si (a se olorun mo si)
a se olorun da mi mo (a se olorun da e mo)
gbogbo ohun ti mo la koja laye
(orin re lo ma gbeyin, oro olorun da e mo)
fun ogo oluwa ni (da e mo)
olorun da e mo o
olorun. da. e…
letras aleatórias
- letra de shotgun - high line
- letra de en pensant à nous - hyacinthe
- letra de i'm sorry - shepard
- letra de rain is gone - tom tukker
- letra de matrouhiche - magic orano
- letra de the right paige - paigey cakey
- letra de hype - luxus & doon
- letra de happy - thegoodperry
- letra de monochromatyczność - markoprotocrew
- letra de scarpe bianche - disme