letra de health is wealth - 9ice
ha….yeaaaa
e ribi 9ice ati kwam ara ba nbi
if you wanna live long
if you wanna stay strong
if you wanna live long and stay strong
ile la loro (ile la loro)
dokita a fun e ni imoran heh
if you wanna live long and stay strong
ile la loro (ile la loro)
dokita a fun e ni imoran heh
ogun ibile afun ni ni iwosan
oloyun a bi were
lai sise abe
ewe nje, ogun nje (kabiyesi o)
ma se logun without doctor’s prescription
mo n tenu mo
mo n tenu mo
call on doctor’s attention
if you need solution
mo n tenu mo adigun heh, mo n tenu mo
to much is given, much is asked of them
ile a loro, ile a loro
if you wanna live long and stay strong
ile la loro (ile la loro)
dokita a fun e ni imoran heh
if you wanna live long and stay strong
ile la loro (ilе la loro)
dokita a fun e ni imoran heh
iwosan ti de o
alaboyun е mu ra o
bo ba se pe eni ba e
akinkoju a su
alaboyun o ni ibi omiran to le lo
ko ja si hospisitu
tori pe ile la loro o
o se dada fun alaboyun sugbon
ema se fi iwosan si ile
e o gbodo da ogun lo o
lai se ase dokita o
if you wanna live long and stay strong
ile la loro (ile la loro)
dokita a fun e ni imoran heh
if you wanna live long and stay strong
ile la loro (ile la loro)
dokita a fun e ni imoran heh
imo toto lo le segun arun gbogbo
efan to gboro
lo wa aran to lero
ki eku ile gba ko so fun ti oko
cleanliness is essential
but your life is potential
and the sound of times on your initial
imo toto bori arun mo le
la se ni ka se itoju fun alaboyun
sheri alaboyun, kef o wo bowo o
eja ka se itoju wa ni ayika wa
if you wanna live long and stay strong
ile la loro (ile la loro)
dokita a fun e ni imoran heh x5
letras aleatórias
- letra de 3mer ezzahi - icosium
- letra de 24th hour - nick jonas
- letra de penny dreadful - professor elemental
- letra de ice - lil nick
- letra de the questions - vocal assassin
- letra de dans ce monde de tarés - g-zon (la meute)
- letra de run the races - santigold
- letra de mmxiv : nouvel ordre - farhaon
- letra de se beber curasse - cristiano araújo
- letra de un coeur en or - nakk mendosa